Kádàrá
Kádàrá (Destiny)
Adánitán ti dá ni tán kí Abanijé tó dé
Nígbàtí Abanijé dé, ó bá ní lówóo atúnniṣe
The scriptures have been written
Kòkúmọ́ will have just a child
Àyòká will know no struggles but greatness
Yèyé Òsun on a mission to rewrite the scripts
Forgetting that Abínú ẹni kò lè pa Kádàrá dà
My soul rejoice in distress
Àbíkú sọ olóógùn dèké
Time will lead adeiu songs at the struggles death
The sphere I occupy only deserve more dedication
Not anticipation of emptiness over failed patterns
Remember endeavor is part of the ingredient
Forget not that Abiyamo di òtá àgàn ,ẹni ńsisé òtá òle
Ó wu agbe kó funfun bíi lékeléke sùgbón Kádàrá ni ò jé
Fate and it sister karma are no respecter of personality
Rather sit with the sculptor from which you picked yours
The fish lives in the water and the dove in air
We cohabitate to manifest different purpose
The Amniotic sac connections
Sùgbón Àyànmóo Táíwò yátò sí ti Kéhìndé
Olanrewaju Ẹbùnoluwa®
This is a good beginning, keep it up. There's always room for improvement.
ReplyDelete