ÀTÙPÀ

ÀTÙPÀ                                     Olanrewaju Ẹbùnoluwa ®

Ojú kìí ti iná ale
That's what my grandma told me
She said Dear son,don't be afraid to shine so bright
So I came out with my light, whilst lighting that of others
The hour came, Osó and others tried to put my light out
Ahh màámi àgbà!!! Why is the world so cruel?

Bí ìmọ́lẹ̀ bá wọlé òkùnkùn á paradà 
That's how grandpa taught me
He said son, tell the truth and see lies disappear always 
So my ninty nine truth ushered in hatred
The world awaiting the single twist in the plot
Olóòótọ kìí kú sí ipò Osikà that's bàámi àgbà watchword

Lẹhìn òkùnkùn bíríbírí ìmọ́lẹ̀ yóò tán
Relax arákùnrin, ni òrò bàbá ọgbọ̀n
The trouble of now will make way for Peace of mind
If only you can keep your candle burning and stay true
This hit the inner cord and vocals of mine to a new song
Ìmọ́lẹ̀ dé 
Oníwà ìbí wábi gba X2

Àtùpà yí ko gbọdọ kú
Not everything happens for a reason
But you meet people for a reason 
And most times things happen for a reason
Tan àtùpà rẹ kí o si fọ ẹyin àtùpà rẹ mọ tóní tóní
Kí àtùpà rẹ lè ràn ẹni tí yó rí ìdí rẹ lọwọ


Comments

Popular posts from this blog

The God's Cruel Jest

The Strands of Marriage in the Era of Divorce

Growing Together, Not Apart: How to Evolve as a Couple